Sportstalk jẹ nkan ti ọ dàbí Mediofficials! (Sportstalk; Another Mediofficials like tribe) - Let's Hope Not!!

avatar

F3-1-REV2-1.jpg
Orísun Àwòrán
A Leader Should Be A Good Listener

Mo le má mọ nipa ọja Steem-Engine tribe daradara, ṣugbọn ohun kan ti Mọ daju ni otitọ nipa mi ni pe, Emi le dajudaju kọ iṣẹ akanṣe tabi iṣowo ti yoo pari ni ipele Dumu kan.

Sportstalk jẹ nkán tí ọ ṣe pàtàkì fún àwọn tí wọn bá fé ṣorò lori ohun ti ọ ṣẹlẹ ní agbègbè awọn ti wọn má gbà bọọlu tàbí orisirisi èrè idaraya ti ọ wa ni agbalaaye. Sùgbón nkan ti mọ ri nipa Sportstalk ni wipe awọn Oludari àti ẹni tí ọ jẹ gẹgẹbi olórí Oludari Sportstalk ko fi igbakan fé ilọsiwaju Sportstalk. Ẹní ti ọ le wo súnsun to má sọ wípé owun kò dá Sportstalk tribe lẹ láti fé kí àwọn èèyàn gbérí níbè, ṣe ìyẹn ni awọn ẹni ti ọ ma wun lati fi ọwọ ràbàtà/Kankan sí níbẹ. - With this price dangling in a not so favorable price for some early investors. Now, even a very successful opportunist can never invest in such a failed tribe.

iPhone IMG.png
iPhone IMG-20191225-WA0017.jpg

Just like Mediofficials, ẹní ti ọ jẹ wípé owun lo da Mediofficials lè jé èyán bí ẹní tó ní Sportstalk tí mo ṣorò nípa é nsìn. Kódà, wón kó yatọ rárá. Ìyen ni wipe kó sí nkán tí ọ kan owun pẹlú àwọn tí wọn tí ra Mediofficials token. Nibayi, awọn tí wọn ra Mediofficials token su'kun abamọ pé àwọn koba má tí lọ ra RaraRada ti won ra.

Kò má bà jẹ nkán tí ọ ma regret/ had I know / kabamo... Iwọ tí ọ bá mọ wipe ọ jẹ ìkan lára àwọn tí ọ ni ọwọ/Sports token repete ni Account é. It's better you yọ́ owó rè ni Sportstalk nitori wípé Sportstalk má dàbí Mediofficials very soon.



0
0
0.000
2 comments
avatar

Have you looked at the newest, and according to a lot of people, the best up and coming sports community on the Steem blockchain? (And not the SteemEngine tribe sidechain). Join Sportsball, where we talk about sports, and balls, and sometimes both: https://beta.steemit.com/trending/hive-196481

0
0
0.000
avatar

Congratulations @all4all! You have completed the following achievement on the Steem blockchain and have been rewarded with new badge(s) :

You received more than 50 upvotes. Your next target is to reach 100 upvotes.

You can view your badges on your Steem Board and compare to others on the Steem Ranking
If you no longer want to receive notifications, reply to this comment with the word STOP

Vote for @Steemitboard as a witness to get one more award and increased upvotes!
0
0
0.000